Mattewu Ori Kejo

1 Nígbátí Jésù sì ti sọ̀kálè láti orí-òkè, ọ̀pòlọpọ àwon ènìyàn s` tọ̀ ọ́ lèyín. 2 Sì wó, adẹ̀tẹ́ kan sì wá sí ọ̀dọ̀ rẹ̀, ó sì wó'lè níwájú rẹ̀, ó wípé, "Olúwa", bí iwọ́ bá fẹ́, o leé sọ mí di mímó." 3 Jésú sí na ọwọ́ rẹ̀, ò ṣì fi kàn an, ó wí pé, " èmí fẹ́, di mímó". Lọ́gán, a sí fọ̀ ọ́ m` kúrò nínú ẹ̀tẹ̀ rẹ̀. 4 Jèsú sí wí fún pé, "ri wipé o kó sọ ohunkóhun fún ẹnikẹ́ni. lọ ní ọ̀n´ rẹ, á tí wípé kí o fi ara rẹ hàn fún wolíì kí o sì pèsè ọrẹ tí Mòósé paláse, kí ó baá le jẹ́ ẹ̀rí fún wọn. 5 Ǹigb´àti Jésù sì wọ Kápánáùmú, Balógun ọrún kan si tọ ó wá ó sí bérè lọ́wọ́ rẹ̀, 6 pé, "Olúwa," òsìsẹ́ mi dùbúlè ní ilé ńipò àilérin ǹinú ìrora ńlá". 7 Jésù wí fún pé, émi yóò wá láti wóó sán. 8 Balọgun ọ́rùn náà sì dáa lóhùn pe, "Olúwa", emi kó yẹ ní ènìyàn tí ìwo o bá wọ abẹ́ òrùlé mi, kìkì ki sọ́ ọrọ̀, òsìsẹ́ mi yóò sì wó sán. 9 nitóòtọ́ pé pèlú jẹ́ énìyàn kan tí ó wà nì abẹ́ àsẹ, mo sì ní ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ ọmọogun, là bẹ́ mí. mo sì sọ fún ẹnìkan pé "lọ", yóò sì lọ, fún ẹlómíràn pé "wá" yóò sí wá. fún awon omo du mi se e yi" yo si se. 10 Nígbàtí Jésù sí gbọ́ àwọn ọrọ́ wọ̀n yí, ọkàn rẹ́ yọ, ó sí wí fún àwọn ènìyán tí wó báá rin pé, " nítọ́ọ̀tó, ni mo wí fún ún yin, emi kò rí ènìyán bíì ará ọkunrín yí pélù ìgbàgbọ́ yí ní Israẹ́lì. 11 Mo wí fún yín pé, ọ̀pòlọpò ènìyàn yóò wà làtí ìlà-òòrùn, atí ìwò-òòrùn, ati wí pè, wón sí jókò olórì tábìlì pèlú Àbàráhàmù, ìsákì, ati Jakọ́bù ní ìjọba Olọ́run. 12 Ṣugbọ́n àwọn ọmọ ìjọba ni a o si sọ sí ìnú òkúnkùn biribiri, ǹibití ẹkún àti ọ̀pọ́lọpọ̀ ikoro wá." 13 Jésù sí wí fún balogun ọ̀orún pé, "lọ bí o ti gbàgbó, yóò sí rẹ̀ fún ọ bẹ́è gẹ́gẹ́, òsìsé re si gba ìwósan ní déédé àkókò náà. 14 Nígbàtí Jésù sí wá sí ilé Pétérù, órí màmá ìyàwó rẹ́, tí ó sùn nínù àìsàn ibà. 15 Jésù sì fí ọwọ́ kán-àn, àìsán ib` sì fií sí lè. O sì dìde ó síí bẹ̀ rẹ̀ sí se iránsé fún un. 16 Nígbàtí ó di ìròlẹ́, awọn ènìyàn sí gbé àwọn orisirisi ènìyàn wá sí wàjù Jésù, tí ẹ̀mí òkùnkún joba lọ̀rí wọọ. O sí lé gbogbo ẹ̀mí òkùnknù jade pèlú ọ̀rọ́, Ò sí wò wọ́n sàn gbogbo awọ́n tí wọ̀ sàì sè n. 17 È yì sẹlẹ ki orọ́ tí o tí ẹnú awọn wolìí sọ lẹẹ wá sí imú pé ohún fún ara ré kó gbogbo ìsẹsùn wa lo. 18 Nígbàtí Jésù rí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn tí wón yìikán, ó fún wón ní ímọ́rán látì lọ sí òdi kèjì omi Gàlìlíì. 19 Nìgbànáà ni awọn akọ̀wé tọ̀ọ́ wà ní ibi ti o wá, wọ́n sí wí fún pé, " Olùkó, ẹni yo ba ọ́ lo ní bí tí o ba lo." 20 Jesu sí wí fún pẹ́, àwọ́n kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀ ní ilé tí wọ́n gbé, bẹ́ẹ̀ni ẹyẹ nìí íbì tí ó sún, súgbón, ọmọ enìyàn kò ní ilé tàbí ìbí tí yóò sùn sí. 21 Ẹníkan nínú àwọn ọmọ lẹ́yìn rẹ́ wí fún pẹ́, " Olúwa, fún mí ní áyà láti lọ sin bàbá mí ." 22 Ṣùgbón Jèsú wí fún pé, " tẹ̀ lẹ́ mí, kí o sí fí ókú sínsín sílé fún àwọn tí wó ní okú. 23 Nìgbátí Jesu wọ ọkọ̀ ojú omi, àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ sì tẹ̀le wọ lé. 24 Sì wòọ́, ló ji jì, ìjì lí le bẹ̀rì sí ní fẹ́ lórí omi, àti wí pé ọkọ̀ ojú omi sì fẹ́ pa ojú dé sí nìnú omi, ṣùgbọ́n Jesu ti sùn. 25 Àwón ọmọ èyìn rẹ̀ sì wá bá wọ́n sì jìí dìde, wọ́n wí fun pé, " gbà wá, Olúwa; gbogbo wa ti fẹ́ kú!" 26 Jesu sì wí fún we pe, " kí ló de ti a si bẹ̀rù. ẹ̀yan onígbàgbó kékèékí?" Ó sì dìde, ó bá ìjì nàá wí àti omi, lọ́ gán, ìdákẹ́ rọ́rọ́ sì wà lọ́rì omi. 27 Ẹnu sì ya àwọn ẹ̀nìyán wọn sì wí pé, "irú ènìyàn wo ni eyí tí afẹ́fẹ́ àtí ìjì sí gbọ́ ti rè?. 28 Nìgbàtí Jesu sì ti ré kọjá sí odì kejì sí ìlú Gádárà, Ọkùnrin méjì kan tí ẹ̀mí èsù ń jọba lọrí wọn o p`d´ rẹ̀. won n jáde láti inú ibojí bíì dìgbòlugí tọ́ bẹ̀ ti àwọn arìn rìn ajò kè le ẹ̀ kọjá ní ọná náà 29 . Sí woó, wọ́n kígbe lóhún rara wípé, "kìni ó sẹ ta wa tì rè, iwọ ọmọ Ọlọ́run? Ìwọ ti wá làti pọ́nwa lójú kí ó tó tó ákókò? 30 Agbo ẹlẹ́dẹ̀ púpo kan ǹjẹun nítòsí ibẹ̀. 31 Àwọn ẹ̀mí èsù náà bẹ Jesu wí pé "bí o ba lé wa já de, le wa ja de sínu agbo ẹlẹ́dẹ̀ tí wo nìtósì yìí ." 32 Jesu sí sọ fún wọn pe, "e máa lọ sí ibẹ́. àwọn ẹ̀mi èsú náà sì lọ sì agbo ẹlẹ̀dẹ̀ nàa; sì wóò, àwọn ẹlẹ̀dẹ̀ nàa sì sà ré sọ̀kalè lọ sìnú òkun wọ̀n sì sègbé. 33 Gbogbo àwọn tí wọn nítọ̀jú agbo ẹlẹ̀dẹ̀ nàa sì sàlọ sìnú ilú, wọ̀n sì sọ ohun gbogbo tí ó sẹlẹ́ sì àwọn ọkùnrin èsú nàa. 34 Sì wó, gbogbo àwọn ará-ilú náà jáde pàde Jesu. Nígbàtí rii wọn bẹ̀é, kí o f agbegbe won sile.