Orí kerin

1 Emi wi fun yin pe bi ajogún ba wa ni ewe, ko yato si ẹru, sugbọn oun lo ni gbobo ogun naa. 2 Oun si mbẹ labẹ itọni lọwọ awọn olutọju ati iriju titi di akoko ti baba rẹ ti yan. 3 Ati nigbanaa, t'awa l'ọmọde, awa wa ni onde labẹ ipilẹṣẹ ẹda. 4 Sùgbọń nigbati akoko kikun de, Ọlọ́run rán ọmọ rẹ̀, tí a bí ninu obinrin, ti a sì bí labẹ òfin. 5 Oun si ṣe eyi lati ra swọn ti mbe labẹ òfin pada, ki wọn sì ri isọdọmọ gbà. 6 Ati wipe bí eyin ti di ọmọ, Ọlọ́run tí rán ẹ̀mí ọmọ rè si inu ọkan yin, ti a fi n kigbe "Abba Baba". 7 Ẹyin kò sì jẹ ẹrú mọ́, bikoṣe ọmọ, ati bi ẹyin ba si tí di ọmọ, ẹyin naa jẹ ajogun nipasẹ Ọlọ́run. 8 Sùgbọ́n ní àkókò naa, nigbati ẹ̀yin kò mọ Ọlọ́run, ẹ̀yin nsiru fún àwọn tí kò ń ṣe Ọlọ́run bíkò ṣe nípasẹ̀ agbára wọn. 9 Níwọ̀n gbà tí ẹ sí tí mọ Ọlọ́run tàbí kí a sọ pé Ọlọ́run ti mọ̀ yín, báwo ni ẹ tún ṣe ń padà sí ìpilèsè aláìlera àti asán? Ǹjẹ́ ẹ̀yin tún fẹ́ padà wa sinru? 10 Ẹ̀yin nkiyesi ọjọ́ àti oṣù àti àkókò àti ọdún. 11 Ẹ̀rù nyin mbà mí, kí o má bà jẹ pe laala asán ní mò n ṣe lóri yín. 12 Ará, mo bẹ̀ yin, ẹ dà bí emí: nítorí emí na dà bí ẹ̀yin. Ẹ ko si ṣe mi ni ibi kankan. 13 Sùgbọ́n e mọ̀pé nitorii àìsàn ara ni mofe wààsù ìhìnrere fún yín ní ìgbà ìsájú. 14 Bí ótiwulèjépé ìlera ara à mi fiyínsí ìdáwò, èyin kòkọ̀mí béèni èyin kòsì tamínù. Dípò èyin gbàmí bii eni pé mojé angeli olorun tàbí Jésù tìkalárarè. 15 Níbo, nigbana ni ìbùkún yín gbáwà ni ìsisìyí? nitori mojẹri yín pé, tí óbáseése, èyin lee yọọ ojú yín fúmi. 16 Nitorina, ìhinjé èmi wá di òtáyín bíí nitoriti mò ún bayin sọ òdodo? 17 Wọ́n ìtara lati jèrè yín,sùgbón tíkòsí ìwúlò kankan. Wọ́n fẹ́ payín lẹ́lumọ́, kí ẹleba ní ìtara fún wọn. 18 Ohun tó dára lati ní ìtara fún ète rere, kisiiṣe nígbátí mobáwà pèlú yín nìkan. 19 Ẹ̀yin ọmọ mi, lẹkansi mowà ninu ìrora ìrọbí fun yin títí ao fifi krísítí múlẹ̀ ninu yín. 20 Ówùmí lati wà pelu yín ní ìsinsìyí lati yí ohùn mi padè, nitoripe moní àníyàn nípa yín. 21 Sọ fún mi, ẹ̀yin tí ẹfé lati wà lábẹ́ òfin, ìhínjẹ́ èyin ún tẹ́tísí òfin bí? 22 Nitoriti akọ nípati abrahamu pe óní ọmọkùnrin méjì, òkan nipati ẹrúbìnrin rẹ̀ àti òkan nípa arábìrirè. 23 Sùgbọ́n èyítí abí nípa erúbìnrin naa jé nípati ara, sùgbọ́n abí ìkejì lati ara arábìnrin rẹ̀ nípa ìlérí. 24 Ǹkan wọ̀nyí ni a fí ńṣe àpẹrẹ, nítorí àwọn obìnrin yìí dúró fún májẹ̀mu méjì. Ọ̀kan làti òkè Sínai tí o sí bi àwọn ọmọ tí wọ́n di ẹrú. Eyi ni Hágárì. 25 Nisisiyi, Hágárì dúró fún òkè Sínai ní Arábia, oun sí duro fún Jerusalemu àkokó yìí, nítorí oun pèlú àwọn ọmọ rè l'oko ẹrú. 26 Jerusalemu ti òkè jẹ́ ọ̀fé, òhún sìjẹ́ ìyá wa. 27 akọ wípé,'' ẹyọ̀,ẹ̀yin àgàn tíkòbí.Ẹpariwo kí esí hóó, ẹ̀yin tíkò la ìrora ìbíkọjá. nitoripe àwọn ọmọ tí ìyá tikòsílẹ̀ ni opọ̀ ju àwọn obìnrin tí óní ọkọ lọ.'' 28 Sùgbọ́n, ẹ̀yin ara, bi ísákì, ni àwọn ọmọ ìléri 29 Ni àkókò naa èyítí abí nipati ara ún se inúnibíni sí èyítí abí nípa ti ẹ̀mí. Bẹẹni órí nísisìyí 30 kínni ọ̀rọ́ olorun wí? ''lejade, erúbìnrin na àti ọmọrè. Nitoripe ọmọ ẹrú na ki yio ní ìpín ninu ogún pẹ̀lú ọmọ òmìnira obìnrin naa 31 Nitorina, èyin ara,àwa kìíse ọmọ ẹrúbìnrin naa bíkòse, ọmo òmìnira obìnrin