Orí Kẹtàdínlogún

1 Lẹ́yìn tí Jésù sọ́ nkán wọ́n yí tán, ò gbé òjú sí òké sí ọrún o sí wìpé, "Bábá, wákàtí na ti dé, yín ọmọ Rẹ́ lògó kí ọmọ Rẹ́ leé yín ọ́ lògó - 2 gẹ́gẹ́ bí O ṣé fún ní àṣẹ́ lorí gbogbo ẹran ara kí o lè fí iyè ayérayé fun gbogbo àwọn tí ẹ ti fí fun. 3 Eyí ni iyé ayérayé: wípé wọ́n mọ́ ọ́, Ọlọ́run olótìítọ́ kàn ṣoṣo, àti ẹní tí iwọ̀ rán, Jésù Kristi. 4 Èmí yìn ọ́ ní ogo ní aiyé. Emí ti parí iṣẹ́ tí ẹ fún mi látí ṣe. 5 Nisísínyí, Bàbá, yìn mí lógo pẹlu ara rẹ, pẹlú ogo ti mo ni latí íbẹ́rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ wá kí á tó dá ayé. 6 Mo fí orúkọ rẹ hàn fún gbogbo àwọ́n tí o fi fún mi láti inú ayé. Àwọn ni tìrẹ, ìwọ sì fi wọ́n fún mí, àwọn sì ti pa ọ̀rọ̀ rẹ̀ mọ́. 7 Nísinsìnyi wọ́n mọ̀ wípé gbogbo ohun ti ẹ̀yin fi fún mi wá ni àti ọ̀dọ̀ rẹ̀, 8 nítorí èmi ti fún wọn ni gbogbo ọrọ ti ẹ fi fún mi. Àwọn ti gba wọ́n, àwọn sì ti mọ̀ wípé ẹ̀yin ni ó rán mi. 9 Èmí gbádúrá fún wọ́n. Èmi kò gbàdúrà fún ayé ṣùgbọ́n fún àwọn ti ẹ fi fún mi, nìtorí àwọn ní tìrẹ́. 10 Àwọn ohún ti ṣé títì èmi jẹ́ tirẹ́, àti gbogbo àwọn ohun tí ṣe tìrẹ jẹ́ tí emì, a sí yín mi ni ògo nínú wọ́n. 11 Emí kò si nínú ayé mọ́, ṣùgbọ́n awọ́n wọ̀nyí ṣì wà nínú ayé, àti wípé èmí ń bọ̀ wá sí ọ̀dọ̀ rẹ. Bàbá Mímọ́, Ẹ pa wọ́n mọ́ ní orúkọ Rẹ tí Ẹ fi fún mi kì wọ́n ó lé wà ní ìṣọ̀kan, gẹ̀gẹ́ bí àwa ṣe wà ní ọ̀kán. 12 Nígbà ti mó ṣi wa pẹ̀lú wọ́n, èmi pá wọ́n mọ̀ ni orúkọ rẹ̀ ti ìwọ́ fí fún mì. Èmi dáàbò bó wọ́n, atí wìpé ko sí ọ̀kán nínú wọ́n ti o ṣègbé àyàfi ọmọ ègbé, ki iwè mímọ lé dì mímù ṣẹ̀. 13 Nísisìnyí èmi n bọ́ sì ọ̀dọ̀ yín, ṣùgbọ́n èmi n sọ́ awọn nkán wọ́nyì nínú ayé ki wọ́n ò lé ní ayọ̀ mi ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ nínú wọn. 14 Èmi ti fí ọ̀rọ̀ rẹ́ fún wọn, awọ́n aráyé sì tí kórìíra wọn nítorí wọn kìí ṣe ti ayé, gẹ́gẹ́ bí èmi náà kìí ṣe ti ayé. 15 Èmi kò bèèrè wípé kí ẹ mú wọn kúrò ní ayé, ṣùgbọ́n kí ẹ̀yin kí ó pa wọn mọ́ lọ́wọ́ àwọn ẹni ibi. 16 Àwọn kìí ṣe ti ayé, gẹ́gẹ́ bí èmi náà kìí ṣe ti ayé. 17 Ẹ́ yà wọn sọ́tọ̀ pẹ̀lú òtítọ́. Òtítọ́ ni ọ̀rọ̀ rẹ̀. 18 Gẹ́gẹ́ bí ìwọ ṣe ránmi wá sí ayé, gẹ́gẹ́ bẹ́ẹ̀ ni mo rán wọn sínú ayé. 19 Nítórí tiwọn mo yara mi sọ́tọ̀, kí àwọn náà le di yíyà sọ̀tọ̀ nínú otítọ́. 20 N kò gbàdúrà fún àwọn yí nìkan, ṣùgbọ́n fún gbogbo àwọn tí wọn bá gbàgbọ́ nínú mi nípasẹ̀ ọ̀rọ̀ wọn pẹ̀lú. 21 Kí gbogbo wọn le wà ní ọ̀kan, gẹ́gẹ́ bí ìwọ, Bàbá, ṣe wà nínú mi, àti èmi nínú rẹ. Mo gbàdúrà kí àwọn náà le wà nínú wa pẹ̀lú, kí àwọn aráyé le gbàgbọ́ wípé ìwọ ni o rán mi. 22 Ògo tí o fì fún mi, mo ti fi fún àwọn náà pẹ̀lú, kí wọn lè wa ní ìṣọ̀kan, gẹ́gẹ́ bí àwa náà ṣe wà ní ọ̀kan: 23 Èmi ní inú wọn, ìwọ ní inú mi- kí a lè mu wọn wà ni ìṣọ̀kan pípé, kí àwọn aráyé le mọ́ wípé ìwọ ni o rán mi, àti wípé o fẹ́ràn wọn gẹ́gẹ́ bí o ṣe fẹ́ràn èmi náà. 24 Bàbá, mo fẹ́ kí àwọn tí ẹ tí fi fún mi wà ní ọ̀dọ̀ mi ní ibi tí mo báwà, kí wọn sì rí ògo mi, ògo tí ẹ ti fì fún mi kí a tó dá ayé nítori ẹ fẹ́ràn mí. 25 Bàbá Olódodo, àwọn aráyé kò mọ̀ọ́, ṣùgbọ́n èmi mọ̀ọ́; àwọn eléyìí mọ́ wípé ìwọ ni o rán mí. 26 Èmi jẹ́ kí orúkọ rẹ dí mímọ̀ fún wọn, èmi yóò sí tún jẹ́ kí o di mímọ̀ síi kí ìfẹ́ tí ìwọ fi fẹ́mi lewà nínú wọn, èmi yóò sì wà nínú wọn.