Orí Kejì

1 Lẹ́yìn ọdún mẹ́rìnlá, mo gòkè lọ sí Jerúsalẹ́mù pẹ̀lú Bánábásì ati Títù pẹ̀lú mi. 2 Mo gòkè lọ nìtorì irán (ífihán) ìyìnréré tí mo ní láti kèdé larin àwon kèfèrí. Mo bá àwọn tó dàbí pẹ́ wọ́n ṣe pàtàkì sọ̀rọ̀ ní ìkọ̀kọ̀ kọ́ le baà dá mi lójú pe ẹ̀mi kò sáré lásán. 3 5 Àti pẹ̀lú pe Títù, tó wà pẹ̀lú mi tó jé ará Gíríkì, a kò fi ipá kọọ́ ní ilà. 4 Àwọn èké arákùnrín wà ní ìkọ̀kọ̀ láti wá ṣe amín òmìnira tí a ní nínú Krístì Jésù. Wọ́n fẹ́ láti sọ wá di ẹrú, 5 sùgbón áwá kò fi ìgbà kankan gbà fún wọn, nítorí kí otítọ́ ìhìnréré le wà pẹ̀lú wa. 6 Ṣùgbón àwọn tó da bí pé wọ́n ṣe pàtàkì (gbógbó ohun tó dà bí pé wọ́n jẹ kó se pàtàkì sí mi, nítorí pé Ọlọ́run kìíṣe ojúsàjú) 7 Ní ìdàkejì wọ́n rí pé áti fi ìhìnréré sí àwọn áláìkọlà lé mi lọwọ, gẹ́gẹ́ bí a ti fi ìhìnréré sí àwọn tí akọ ní là lé pétéru lọ́wọ́. 8 Nítorí Ọlọ́run, tó siṣẹ nínú pétérù gẹ́gẹ́ bii àpóstélì sí àwọn tí a kọ ní ílà, òhun sì ṣe nínú mi pèlú sí àwọn kèfèri. 10 9 Nígbà tí Jémísì, kéfásì ati Jòánu, tí a dá mọ̀ gẹ́gẹ́ bí àwọn tí o gbé ìjọ ró, tí óye ore-ọ̀fẹ́ tí á fi fún mí ye, wọ́n fún Bánábásì átí èmi ní ọwọ idápọ. Wọ́n ṣè èyí nítorí kí á bà lè lọ sọdọ àwọn kèfèrí àti wípé kí àwón lè ba lọ sí ọdọ àwón tí a kọ ní là 10 Wọ́n bèrè wípé kí á rántí àwọn áláìni, ohun gàngàn tí mò ń làkàkà láti ṣe. 12 11 Ṣùgbón nígbàtí kéfásì lọ sí áńtíókù, mo ta kò lójúkójú, nítorí pé ó se aida. Kó tó di pé àwón árákùnrin kán wá sọ́dọ̀ mi láti ọ̀dọ̀ Jémísi, Kéfásì ńjẹ-ún pẹ̀lú àwón kèfèrí. Ṣùgbọ́n nígbàtí àwón árákùnrin de, o ya kuro lọdọ àwón kèfèrí. O bẹru àwón tí ń bere fun ikọla. 13 Àwon júù yókù darapọ̀ mọ́ àgàbàgebè yìí. Bẹ́è pẹ̀lú Bánábásì sáko lo nípa àgàbàgebè wọn. 14 Ṣùgbón nígbà tí mo rí pé ìwà wọn kò tẹ̀lé otítọ́ pelu ìhìnrere, mo sọ fún kéfásì níwájú gbogbo won, to ba jẹ́ pé jú ni ọ́ tí o sì ńgbé bí kèfèrí tí kì íse bí júu, báwo lo se fi ipá mú àwọ́n kèfèrí láti máa gbé bí ju? 15 Àwa naa jẹ júù nípa ìbí kìí se nípa kèfèrí ẹlẹ́ṣẹ. 16 Nítorí àwa mọ̀ pé akò lè dá èniyan láre nípa íṣẹ́ òfín ṣùgbọ́n nípa ìgbàgbó nínú Jésù Krístì nikan. Nìtorí pé àwa ná gbàgbo nínú Jésù Krístì kí ábà le dáwa láre nípa ìgbàgbọ́ nínú Jésù Krístì, kìí íṣe nípa òfin.Nítorí kò sí ènìyàn ẹlẹ́ran ara tí alè gbàlà nípa òfin. 17 Ṣùgbón ká ní nígba tí àwa na bá ńwa kí á dá wa, láre nínú Krístì, à wa ná jẹ́ ẹlẹsẹ, ǹjẹ́ Jésù ńgbé ẹsẹ ga bi? Rárá ká ma ri. 18 Ǹjẹ́ bí èmí bá tún ohun tí mo ti dàrú kọ́, mo fi ara mí hàn gẹ́gẹ́ bi a rúfin. 19 Nítorí nípa òfin mo kú sí òfin, nítorí kíń ba lè fà wá fún Ọlọ́run. 21 A ti kàn mí mó àgbélebu pẹ̀lú Jésù, kìí íse èmi ni mo wa láyé, ṣugbọn Krístí ńgbé inú mi. Ìgbé ayé tí mò ńgbé nísinsìnyí nínú ẹran ara jé nípa ìgbàgbó nínú ọmọ Ọlọ́run, ẹni tí o fẹ́ràn mi tí ó sì fi ara rẹ̀ sílẹ̀ fún mi. 20 Èmi ko gbé ore-ọ̀fe Ọlọ́run sí apá kan, nítorí pé tí a bá ní òdodo nípasè òfin ajẹ́ wípé Jésù kú lásán.